Lúùkù 23:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Nígbà tí Hẹ́rọ́dù rí Jésù, inú rẹ̀ dùn gan-an. Ó ti pẹ́ tó ti fẹ́ rí Jésù torí ó ti gbọ́ ọ̀pọ̀ nǹkan nípa rẹ̀,+ ó sì ń retí pé kí òun rí i kó ṣiṣẹ́ àmì díẹ̀.
8 Nígbà tí Hẹ́rọ́dù rí Jésù, inú rẹ̀ dùn gan-an. Ó ti pẹ́ tó ti fẹ́ rí Jésù torí ó ti gbọ́ ọ̀pọ̀ nǹkan nípa rẹ̀,+ ó sì ń retí pé kí òun rí i kó ṣiṣẹ́ àmì díẹ̀.