-
Àìsáyà 43:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Torí èmi ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ,
Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì, Olùgbàlà rẹ.
Mo ti fi Íjíbítì ṣe ìràpadà fún ọ,
Mo sì ti fi Etiópíà àti Sébà dípò rẹ.
-
-
Títù 1:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 àmọ́ nígbà tí àkókò tó lójú rẹ̀, ó jẹ́ kí a mọ ọ̀rọ̀ rẹ̀ nípasẹ̀ iṣẹ́ ìwàásù tó fi lé mi lọ́wọ́,+ èyí tí Olùgbàlà wa, Ọlọ́run pa láṣẹ;
-
-
Júùdù 25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Ọlọ́run kan ṣoṣo tó jẹ́ Olùgbàlà wa nípasẹ̀ Jésù Kristi Olúwa wa, ni kí ògo, ọlá, agbára àti àṣẹ máa jẹ́ tirẹ̀ láti ayérayé àti nísinsìnyí àti títí láé. Àmín.
-