Lúùkù 11:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Bó ṣe ń sọ àwọn nǹkan yìí, obìnrin kan kígbe láàárín èrò, ó sọ fún un pé: “Aláyọ̀ ni ilé ọlẹ̀ tó gbé ọ àti ọmú tí o mu!”+
27 Bó ṣe ń sọ àwọn nǹkan yìí, obìnrin kan kígbe láàárín èrò, ó sọ fún un pé: “Aláyọ̀ ni ilé ọlẹ̀ tó gbé ọ àti ọmú tí o mu!”+