Máàkù 9:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Nígbà tí wọ́n dé ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ ẹ̀yìn yòókù, wọ́n rí èrò rẹpẹtẹ tó yí wọn ká, àwọn akọ̀wé òfin sì ń bá wọn jiyàn.+ 15 Àmọ́ gbàrà tí gbogbo àwọn èrò náà tajú kán rí i, ó yà wọ́n lẹ́nu, wọ́n sì sáré lọ kí i.
14 Nígbà tí wọ́n dé ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ ẹ̀yìn yòókù, wọ́n rí èrò rẹpẹtẹ tó yí wọn ká, àwọn akọ̀wé òfin sì ń bá wọn jiyàn.+ 15 Àmọ́ gbàrà tí gbogbo àwọn èrò náà tajú kán rí i, ó yà wọ́n lẹ́nu, wọ́n sì sáré lọ kí i.