-
Jòhánù 12:44Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
44 Àmọ́ Jésù gbóhùn sókè, ó sì sọ pé: “Ẹnikẹ́ni tó bá ní ìgbàgbọ́ nínú mi, kò ní ìgbàgbọ́ nínú èmi nìkan, àmọ́ ó tún ní ìgbàgbọ́ nínú ẹni tó rán mi;+
-