Mátíù 10:12, 13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Tí ẹ bá wọ ilé kan, ẹ kí àwọn ará ilé náà. 13 Tí ilé náà bá yẹ, kí àlàáfíà tí ẹ fẹ́ fún un wá sórí rẹ̀;+ àmọ́ tí kò bá yẹ, kí àlàáfíà látọ̀dọ̀ yín pa dà sọ́dọ̀ yín.
12 Tí ẹ bá wọ ilé kan, ẹ kí àwọn ará ilé náà. 13 Tí ilé náà bá yẹ, kí àlàáfíà tí ẹ fẹ́ fún un wá sórí rẹ̀;+ àmọ́ tí kò bá yẹ, kí àlàáfíà látọ̀dọ̀ yín pa dà sọ́dọ̀ yín.