-
Mátíù 10:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ibikíbi tí ẹnikẹ́ni ò bá ti gbà yín tàbí fetí sí ọ̀rọ̀ yín, tí ẹ bá ń kúrò ní ilé yẹn tàbí ìlú yẹn, ẹ gbọn iyẹ̀pẹ̀ ẹsẹ̀ yín dà nù.+
-
-
Lúùkù 9:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ibikíbi tí àwọn èèyàn ò bá sì ti gbà yín, tí ẹ bá ń kúrò ní ìlú yẹn, ẹ gbọn iyẹ̀pẹ̀ ẹsẹ̀ yín dà nù, kó lè jẹ́ ẹ̀rí lòdì sí wọn.”+
-