2 Sámúẹ́lì 22:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ò ń gba àwọn ẹni rírẹlẹ̀ là,+Ṣùgbọ́n o kì í fi ojú rere wo àwọn agbéraga, o sì ń rẹ̀ wọ́n wálẹ̀.+