Mátíù 11:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Àmọ́ mo sọ fún yín pé, ilẹ̀ Sódómù máa lè fara dà á ní Ọjọ́ Ìdájọ́ jù yín lọ.”+