Jòhánù 4:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Obìnrin ará Samáríà náà wá sọ fún un pé: “Báwo ni ìwọ, tí o jẹ́ Júù, ṣe máa ní kí èmi, obìnrin ará Samáríà fún ọ lómi?” (Torí àwọn Júù kì í ní ohunkóhun ṣe pẹ̀lú àwọn ará Samáríà.)+
9 Obìnrin ará Samáríà náà wá sọ fún un pé: “Báwo ni ìwọ, tí o jẹ́ Júù, ṣe máa ní kí èmi, obìnrin ará Samáríà fún ọ lómi?” (Torí àwọn Júù kì í ní ohunkóhun ṣe pẹ̀lú àwọn ará Samáríà.)+