Mátíù 12:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Ẹnikẹ́ni tí kò bá sí lọ́dọ̀ mi ń ta kò mí, ẹnikẹ́ni tí kò bá sì dara pọ̀ mọ́ mi ń fọ́n ká.+