Mátíù 16:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jésù sọ fún wọn pé: “Ẹ la ojú yín sílẹ̀, kí ẹ sì ṣọ́ra fún ìwúkàrà àwọn Farisí àti àwọn Sadusí.”+ Máàkù 8:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ó wá kìlọ̀ fún wọn lọ́nà tó ṣe kedere pé: “Ẹ la ojú yín sílẹ̀; kí ẹ ṣọ́ra fún ìwúkàrà àwọn Farisí àti ìwúkàrà Hẹ́rọ́dù.”+
15 Ó wá kìlọ̀ fún wọn lọ́nà tó ṣe kedere pé: “Ẹ la ojú yín sílẹ̀; kí ẹ ṣọ́ra fún ìwúkàrà àwọn Farisí àti ìwúkàrà Hẹ́rọ́dù.”+