-
Mátíù 12:31, 32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 “Nítorí èyí, mò ń sọ fún yín pé, gbogbo oríṣiríṣi ẹ̀ṣẹ̀ àti ọ̀rọ̀ òdì la máa dárí rẹ̀ ji àwọn èèyàn, àmọ́ ọ̀rọ̀ òdì sí ẹ̀mí kò ní ìdáríjì.+ 32 Bí àpẹẹrẹ, ẹnikẹ́ni tó bá sọ̀rọ̀ òdì sí Ọmọ èèyàn máa rí ìdáríjì;+ àmọ́ ẹnikẹ́ni tó bá sọ̀rọ̀ òdì sí ẹ̀mí mímọ́, kò ní rí ìdáríjì, àní, nínú ètò àwọn nǹkan yìí* tàbí èyí tó ń bọ̀.+
-