-
Lúùkù 1:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Àmọ́ wò ó! o ò ní lè sọ̀rọ̀, wàá sì ya odi títí di ọjọ́ tí àwọn nǹkan yìí máa ṣẹlẹ̀, torí pé o ò gba àwọn ọ̀rọ̀ mi gbọ́, èyí tó máa ṣẹ ní àkókò tí a yàn fún wọn.”
-