Sáàmù 34:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ebi máa ń pa àwọn ọmọ kìnnìún* tó lágbára,Àmọ́ ní ti àwọn tó ń wá Jèhófà, wọn kò ní ṣaláìní ohun rere.+ Mátíù 6:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 “Torí náà, ẹ máa wá Ìjọba náà àti òdodo Rẹ̀ lákọ̀ọ́kọ́, gbogbo nǹkan mìíràn yìí la sì máa fi kún un fún yín.+ 1 Tímótì 4:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Torí àǹfààní díẹ̀ wà nínú eré ìmárale,* àmọ́ ìfọkànsin Ọlọ́run ṣàǹfààní fún ohun gbogbo, ní ti pé ó ní ìlérí ìwàláàyè ní báyìí àti ìlérí ìwàláàyè ti ọjọ́ iwájú.+
10 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ebi máa ń pa àwọn ọmọ kìnnìún* tó lágbára,Àmọ́ ní ti àwọn tó ń wá Jèhófà, wọn kò ní ṣaláìní ohun rere.+
33 “Torí náà, ẹ máa wá Ìjọba náà àti òdodo Rẹ̀ lákọ̀ọ́kọ́, gbogbo nǹkan mìíràn yìí la sì máa fi kún un fún yín.+
8 Torí àǹfààní díẹ̀ wà nínú eré ìmárale,* àmọ́ ìfọkànsin Ọlọ́run ṣàǹfààní fún ohun gbogbo, ní ti pé ó ní ìlérí ìwàláàyè ní báyìí àti ìlérí ìwàláàyè ti ọjọ́ iwájú.+