-
1 Àwọn Ọba 1:48Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
48 Ọba sì sọ pé, ‘Ìyìn ni fún Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ẹni tó fún mi ní ẹni tó máa jókòó sórí ìtẹ́ mi, tó sì jẹ́ kó ṣojú mi lónìí!’”
-