Mátíù 19:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 “Àmọ́ ọ̀pọ̀ àwọn ẹni àkọ́kọ́ máa di ẹni ìkẹyìn, àwọn ẹni ìkẹyìn sì máa di ẹni àkọ́kọ́.+ Máàkù 10:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Àmọ́ ọ̀pọ̀ àwọn ẹni àkọ́kọ́ máa di ẹni ìkẹyìn, àwọn ẹni ìkẹyìn sì máa di ẹni àkọ́kọ́.”+