-
Ẹ́kísódù 23:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Tí o bá rí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ẹni tó kórìíra rẹ, tí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà ṣubú tí kò sì lè dìde torí ẹrù tó gbé, o ò gbọ́dọ̀ fi sílẹ̀ lọ. Kí o bá a gbé ẹrù náà kúrò.+
-
-
Diutarónómì 22:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 “Tí o bá rí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ tàbí akọ màlúù arákùnrin rẹ tó ṣubú lójú ọ̀nà, má mọ̀ọ́mọ̀ mójú kúrò. Rí i dájú pé o bá a gbé ẹran náà dìde.+
-