ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 10:37
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 37 Ẹnikẹ́ni tó bá nífẹ̀ẹ́ bàbá tàbí ìyá jù mí lọ kò yẹ fún mi; ẹnikẹ́ni tó bá sì nífẹ̀ẹ́ ọmọkùnrin tàbí ọmọbìnrin jù mí lọ kò yẹ fún mi.+

  • Lúùkù 18:29, 30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Ó sọ fún wọn pé: “Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, kò sí ẹni tó fi ilé sílẹ̀ tàbí ìyàwó, àwọn arákùnrin, àwọn òbí tàbí àwọn ọmọ nítorí Ìjọba Ọlọ́run,+ 30 tí kò ní gba ìlọ́po-ìlọ́po sí i lásìkò yìí àti ìyè àìnípẹ̀kun nínú ètò àwọn nǹkan tó ń bọ̀.”*+

  • Jòhánù 12:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ràn ẹ̀mí* rẹ̀ ń pa á run, àmọ́ ẹnikẹ́ni tó bá kórìíra ẹ̀mí* rẹ̀+ nínú ayé yìí máa pa á mọ́ fún ìyè àìnípẹ̀kun.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́