Mátíù 16:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Jésù wá sọ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ pé: “Tí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ máa tẹ̀ lé mi, kó sẹ́ ara rẹ̀, kó gbé òpó igi oró* rẹ̀, kó sì máa tẹ̀ lé mi.+ Máàkù 8:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Lẹ́yìn náà, ó pe àwọn èrò àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ sọ́dọ̀, ó sì sọ fún wọn pé: “Tí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ máa tẹ̀ lé mi, kó sẹ́ ara rẹ̀, kó gbé òpó igi oró* rẹ̀, kó sì máa tẹ̀ lé mi.+ Lúùkù 9:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ó wá sọ fún gbogbo wọn pé: “Tí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ máa tẹ̀ lé mi, kó sẹ́ ara rẹ̀,+ kó máa gbé òpó igi oró* rẹ̀ lójoojúmọ́, kó sì máa tẹ̀ lé mi.+
24 Jésù wá sọ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ pé: “Tí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ máa tẹ̀ lé mi, kó sẹ́ ara rẹ̀, kó gbé òpó igi oró* rẹ̀, kó sì máa tẹ̀ lé mi.+
34 Lẹ́yìn náà, ó pe àwọn èrò àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ sọ́dọ̀, ó sì sọ fún wọn pé: “Tí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ máa tẹ̀ lé mi, kó sẹ́ ara rẹ̀, kó gbé òpó igi oró* rẹ̀, kó sì máa tẹ̀ lé mi.+
23 Ó wá sọ fún gbogbo wọn pé: “Tí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ máa tẹ̀ lé mi, kó sẹ́ ara rẹ̀,+ kó máa gbé òpó igi oró* rẹ̀ lójoojúmọ́, kó sì máa tẹ̀ lé mi.+