-
Máàkù 9:42Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
42 Àmọ́ ẹnikẹ́ni tó bá mú ọ̀kan nínú àwọn ẹni kékeré yìí tó ní ìgbàgbọ́ kọsẹ̀, ó sàn ká so ọlọ mọ́ ọn lọ́rùn, irú èyí tí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ máa ń yí, ká sì jù ú sínú òkun.+
-