Mátíù 24:40, 41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Nígbà yẹn, ọkùnrin méjì máa wà nínú pápá; a máa mú ọ̀kan lọ, a sì máa pa ìkejì tì. 41 Obìnrin méjì á máa lọ nǹkan lórí ọlọ; a máa mú ọ̀kan lọ, a sì máa pa ìkejì tì.+
40 Nígbà yẹn, ọkùnrin méjì máa wà nínú pápá; a máa mú ọ̀kan lọ, a sì máa pa ìkejì tì. 41 Obìnrin méjì á máa lọ nǹkan lórí ọlọ; a máa mú ọ̀kan lọ, a sì máa pa ìkejì tì.+