Mátíù 19:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Mo tún ń sọ fún yín pé, ó rọrùn fún ràkúnmí láti gba ojú abẹ́rẹ́ kọjá ju fún ọlọ́rọ̀ láti wọ Ìjọba Ọlọ́run.”+ Máàkù 10:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ó rọrùn fún ràkúnmí láti gba ojú abẹ́rẹ́ kọjá ju fún ọlọ́rọ̀ láti wọ Ìjọba Ọlọ́run.”+
24 Mo tún ń sọ fún yín pé, ó rọrùn fún ràkúnmí láti gba ojú abẹ́rẹ́ kọjá ju fún ọlọ́rọ̀ láti wọ Ìjọba Ọlọ́run.”+