Mátíù 25:26, 27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ọ̀gá rẹ̀ fún un lésì pé: ‘Ẹrú burúkú tó ń lọ́ra, o mọ̀ àbí, pé mò ń kárúgbìn níbi tí mi ò fúnrúgbìn sí, mo sì ń kó ọkà jọ níbi tí mi ò ti fẹ́ ọkà? 27 Tó bá rí bẹ́ẹ̀, ó yẹ kí o ti kó owó* mi lọ sí báǹkì, tí mo bá sì dé, ǹ bá ti gbà á pẹ̀lú èlé.
26 Ọ̀gá rẹ̀ fún un lésì pé: ‘Ẹrú burúkú tó ń lọ́ra, o mọ̀ àbí, pé mò ń kárúgbìn níbi tí mi ò fúnrúgbìn sí, mo sì ń kó ọkà jọ níbi tí mi ò ti fẹ́ ọkà? 27 Tó bá rí bẹ́ẹ̀, ó yẹ kí o ti kó owó* mi lọ sí báǹkì, tí mo bá sì dé, ǹ bá ti gbà á pẹ̀lú èlé.