Lúùkù 2:51 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 51 Ó wá tẹ̀ lé wọn sọ̀ kalẹ̀, wọ́n pa dà sí Násárẹ́tì, ó sì ń gbọ́ràn sí wọn lẹ́nu.*+ Bákan náà, ìyá rẹ̀ rọra fi gbogbo ọ̀rọ̀ yìí sọ́kàn.+
51 Ó wá tẹ̀ lé wọn sọ̀ kalẹ̀, wọ́n pa dà sí Násárẹ́tì, ó sì ń gbọ́ràn sí wọn lẹ́nu.*+ Bákan náà, ìyá rẹ̀ rọra fi gbogbo ọ̀rọ̀ yìí sọ́kàn.+