ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Míkà 7:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Torí ọmọkùnrin ń tàbùkù sí bàbá rẹ̀,

      Ọmọbìnrin ń bá ìyá rẹ̀ jà,+

      Ìyàwó ń gbógun ti ìyá ọkọ rẹ̀;+

      Ará ilé ẹni ni ọ̀tá ẹni.+

  • Máàkù 13:12, 13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Bákan náà, arákùnrin máa fa arákùnrin lé ikú lọ́wọ́, bàbá máa ṣe bẹ́ẹ̀ sí ọmọ, àwọn ọmọ máa dìde sí àwọn òbí, wọ́n sì máa pa wọ́n.+ 13 Gbogbo èèyàn sì máa kórìíra yín nítorí orúkọ mi.+ Àmọ́ ẹni tó bá fara dà á* dé òpin+ máa rí ìgbàlà.+

  • Ìṣe 7:59
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 59 Bí wọ́n ṣe ń sọ òkúta lu Sítéfánù, ó bẹ̀bẹ̀ pé: “Jésù Olúwa, gba ẹ̀mí mi.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́