-
Mátíù 24:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín pé, ó dájú pé ìran yìí ò ní kọjá lọ títí gbogbo nǹkan yìí fi máa ṣẹlẹ̀.
-
-
Máàkù 13:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín pé, ó dájú pé ìran yìí ò ní kọjá lọ títí gbogbo nǹkan yìí fi máa ṣẹlẹ̀.+
-