Róòmù 12:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ẹ jẹ́ kí ìrètí tí ẹ ní máa fún yín láyọ̀. Ẹ máa fara da ìpọ́njú.+ Ẹ máa tẹra mọ́ àdúrà gbígbà.+ Éfésù 6:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 pẹ̀lú onírúurú àdúrà + àti ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀, ẹ máa gbàdúrà ní gbogbo ìgbà nínú ẹ̀mí.+ Nípa bẹ́ẹ̀, ẹ wà lójúfò, kí ẹ máa rawọ́ ẹ̀bẹ̀ nígbà gbogbo nítorí gbogbo àwọn ẹni mímọ́. 1 Pétérù 4:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àmọ́ òpin ohun gbogbo ti sún mọ́lé. Torí náà, kí ẹ máa ronú jinlẹ̀,+ kí ẹ sì wà lójúfò,* kí ẹ lè máa gbàdúrà.+
18 pẹ̀lú onírúurú àdúrà + àti ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀, ẹ máa gbàdúrà ní gbogbo ìgbà nínú ẹ̀mí.+ Nípa bẹ́ẹ̀, ẹ wà lójúfò, kí ẹ máa rawọ́ ẹ̀bẹ̀ nígbà gbogbo nítorí gbogbo àwọn ẹni mímọ́.
7 Àmọ́ òpin ohun gbogbo ti sún mọ́lé. Torí náà, kí ẹ máa ronú jinlẹ̀,+ kí ẹ sì wà lójúfò,* kí ẹ lè máa gbàdúrà.+