Jòhánù 13:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Gbogbo yín kọ́ ni mò ń bá wí; mo mọ àwọn tí mo ti yàn. Àmọ́ èyí jẹ́ torí kí ìwé mímọ́ lè ṣẹ+ pé: ‘Ẹni tí a jọ ń jẹun ti jìn mí lẹ́sẹ̀.’*+
18 Gbogbo yín kọ́ ni mò ń bá wí; mo mọ àwọn tí mo ti yàn. Àmọ́ èyí jẹ́ torí kí ìwé mímọ́ lè ṣẹ+ pé: ‘Ẹni tí a jọ ń jẹun ti jìn mí lẹ́sẹ̀.’*+