-
Mátíù 26:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Ọ̀rọ̀ yìí bà wọ́n lọ́kàn jẹ́ gan-an, gbogbo wọn wá bẹ̀rẹ̀ sí í sọ fún un lọ́kọ̀ọ̀kan pé: “Olúwa, èmi kọ́ o, àbí èmi ni?”
-
-
Máàkù 14:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Ẹ̀dùn ọkàn bá wọn, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í sọ fún un lọ́kọ̀ọ̀kan pé: “Èmi kọ́ o, àbí èmi ni?”
-
-
Jòhánù 13:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Àwọn ọmọ ẹ̀yìn wá bẹ̀rẹ̀ sí í wo ara wọn, torí ọ̀rọ̀ náà rú wọn lójú, wọn ò mọ ẹni tó ń sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀.+
-