Jòhánù 18:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Pílátù wá bí i pé: “Kí ni òtítọ́?” Lẹ́yìn tó sọ èyí, ó tún jáde lọ bá àwọn Júù, ó sì sọ fún wọn pé: “Mi ò rí i pé ó jẹ̀bi kankan.+
38 Pílátù wá bí i pé: “Kí ni òtítọ́?” Lẹ́yìn tó sọ èyí, ó tún jáde lọ bá àwọn Júù, ó sì sọ fún wọn pé: “Mi ò rí i pé ó jẹ̀bi kankan.+