Jòhánù 19:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ó ru òpó igi oró* náà fúnra rẹ̀, ó sì lọ síbi tí wọ́n ń pè ní Ibi Agbárí,+ ìyẹn Gọ́gọ́tà lédè Hébérù.+ 18 Ibẹ̀ ni wọ́n ti kàn án mọ́gi+ pẹ̀lú ọkùnrin méjì, ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn wà ní ẹ̀gbẹ́ rẹ̀, Jésù sì wà ní àárín.+
17 Ó ru òpó igi oró* náà fúnra rẹ̀, ó sì lọ síbi tí wọ́n ń pè ní Ibi Agbárí,+ ìyẹn Gọ́gọ́tà lédè Hébérù.+ 18 Ibẹ̀ ni wọ́n ti kàn án mọ́gi+ pẹ̀lú ọkùnrin méjì, ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn wà ní ẹ̀gbẹ́ rẹ̀, Jésù sì wà ní àárín.+