ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 11:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Ní ọjọ́ yẹn, gbòǹgbò Jésè+ máa dúró bí àmì* fún àwọn èèyàn.+

      Ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni àwọn orílẹ̀-èdè máa yíjú sí fún ìtọ́sọ́nà,*+

      Ibi ìsinmi rẹ̀ sì máa di ológo.

  • Àìsáyà 42:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 “Èmi Jèhófà, ti pè ọ́ nínú òdodo;

      Mo ti di ọwọ́ rẹ mú.

      Màá dáàbò bò ọ́, màá sì fi ọ́ ṣe májẹ̀mú fún àwọn èèyàn náà+

      Àti bí ìmọ́lẹ̀ àwọn orílẹ̀-èdè,+

  • Àìsáyà 49:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Ó sọ pé: “Ti pé o jẹ́ ìránṣẹ́ mi nìkan ò tó,

      Láti gbé àwọn ẹ̀yà Jékọ́bù dìde,

      Kí o sì mú àwọn tí a dá sí lára Ísírẹ́lì pa dà.

      Mo tún ti fi ọ́ ṣe ìmọ́lẹ̀ àwọn orílẹ̀-èdè,+

      Kí ìgbàlà mi lè dé gbogbo ayé.”+

  • Ìṣe 13:47
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 47 Nítorí Jèhófà* ti pa àwọn ọ̀rọ̀ yìí láṣẹ fún wa pé: ‘Mo ti yàn ọ́ ṣe ìmọ́lẹ̀ àwọn orílẹ̀-èdè, kí o lè jẹ́ ìgbàlà fún gbogbo ayé.’”+

  • Ìṣe 26:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 pé Kristi máa jìyà+ àti pé bó ṣe jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ tí a máa jí dìde kúrò nínú ikú,+ ó máa kéde ìmọ́lẹ̀ fún àwọn èèyàn yìí àti fún àwọn orílẹ̀-èdè.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́