-
Lúùkù 8:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 bákan náà ni àwọn obìnrin kan tó ti lé ẹ̀mí burúkú kúrò lára wọn, tó sì ti wo àìsàn wọn sàn: Màríà tí wọ́n ń pè ní Magidalénì, tí ẹ̀mí èṣù méje jáde lára rẹ̀; 3 Jòánà+ ìyàwó Kúsà, ọkùnrin tí Hẹ́rọ́dù fi ṣe alábòójútó; Sùsánà; àti ọ̀pọ̀ àwọn obìnrin míì, tí wọ́n ń fi àwọn ohun ìní wọn ṣe ìránṣẹ́ fún wọn.+
-