Ìṣe 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Nígbà tí wọ́n pé jọ, wọ́n bi í pé: “Olúwa, ṣé àkókò yìí lo máa dá ìjọba pa dà fún Ísírẹ́lì?”+