1 Kọ́ríńtì 15:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nítorí lára àwọn ohun tí mo kọ́kọ́ fi lé yín lọ́wọ́ ni ohun tí èmi náà gbà, pé Kristi kú nítorí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa bí Ìwé Mímọ́ ṣe sọ;+ 1 Kọ́ríńtì 15:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 àti pé ó fara han Kéfà,*+ lẹ́yìn náà, àwọn Méjìlá náà.+
3 Nítorí lára àwọn ohun tí mo kọ́kọ́ fi lé yín lọ́wọ́ ni ohun tí èmi náà gbà, pé Kristi kú nítorí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa bí Ìwé Mímọ́ ṣe sọ;+