-
Léfítíkù 12:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Tí ọjọ́ ìwẹ̀mọ́ rẹ̀ fún ọmọkùnrin tàbí ọmọbìnrin bá pé, kó mú ọmọ àgbò ọlọ́dún kan wá sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé fún àlùfáà láti fi rú ẹbọ sísun,+ kó sì mú ọmọ ẹyẹlé tàbí oriri kan wá láti fi rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀.
-