ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 1:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Ó máa bí ọmọkùnrin kan, kí o pe orúkọ rẹ̀ ní Jésù,*+ torí ó máa gba àwọn èèyàn rẹ̀ kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ wọn.”+

  • Jòhánù 1:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Lọ́jọ́ kejì, ó rí i tí Jésù ń bọ̀ lọ́dọ̀ rẹ̀, ó wá sọ pé: “Wò ó, Ọ̀dọ́ Àgùntàn+ Ọlọ́run tó kó ẹ̀ṣẹ̀+ ayé lọ!+

  • 1 Tímótì 1:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ọ̀rọ̀ yìí ṣeé gbára lé, ó sì yẹ ká gbà á délẹ̀délẹ̀, pé: Kristi Jésù wá sí ayé láti gba àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ là.+ Èmi sì ni ẹni àkọ́kọ́ lára wọn.+

  • 1 Jòhánù 4:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Bákan náà, àwa fúnra wa ti rí, a sì ń jẹ́rìí pé Baba ti rán Ọmọ rẹ̀ wá kó lè jẹ́ olùgbàlà ayé.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́