Mátíù 8:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jésù wá sọ fún ọ̀gágun náà pé: “Máa lọ. Bí o ṣe fi hàn pé o nígbàgbọ́, kó rí bẹ́ẹ̀ fún ọ.”+ Ara ìránṣẹ́ náà sì yá ní wákàtí yẹn.+
13 Jésù wá sọ fún ọ̀gágun náà pé: “Máa lọ. Bí o ṣe fi hàn pé o nígbàgbọ́, kó rí bẹ́ẹ̀ fún ọ.”+ Ara ìránṣẹ́ náà sì yá ní wákàtí yẹn.+