6 Àmọ́ kí ẹ lè mọ̀ pé Ọmọ èèyàn ní àṣẹ láyé láti dárí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ jini—” ó sọ fún alárùn rọpárọsẹ̀ náà pé: “Dìde, gbé ibùsùn rẹ, kí o sì máa lọ sílé rẹ.”+
10 Àmọ́ kí ẹ lè mọ̀ pé Ọmọ èèyàn+ ní àṣẹ láti dárí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ jini láyé—”+ ó sọ fún alárùn rọpárọsẹ̀ náà pé: 11 “Mò ń sọ fún ọ, Dìde, gbé ibùsùn rẹ, kí o sì máa lọ sílé rẹ.”
24 Àmọ́ kí ẹ lè mọ̀ pé Ọmọ èèyàn ní àṣẹ ní ayé láti dárí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ jini—” ó sọ fún ọkùnrin tó ní àrùn rọpárọsẹ̀ náà pé: “Mò ń sọ fún ọ, Dìde, gbé ibùsùn rẹ, kí o sì máa lọ sílé rẹ.”+