ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Lúùkù 7:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Bó ṣe sún mọ́ ẹnubodè ìlú náà, wò ó! wọ́n ń gbé òkú ọkùnrin kan jáde, òun nìkan ṣoṣo ni ìyá rẹ̀ bí.*+ Yàtọ̀ síyẹn, opó ni obìnrin náà. Èrò rẹpẹtẹ tún tẹ̀ lé e látinú ìlú náà.

  • Lúùkù 7:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Ló bá sún mọ́ wọn, ó fọwọ́ kan àga ìgbókùú* náà, àwọn tó gbé e sì dúró. Ó wá sọ pé: “Ọ̀dọ́kùnrin, mo sọ fún ọ, dìde!”+

  • Lúùkù 8:52-54
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 52 Àmọ́ gbogbo èèyàn ń sunkún, wọ́n sì ń lu ara wọn bí wọ́n ṣe ń dárò torí ọmọ náà. Torí náà, ó sọ pé: “Ẹ má sunkún mọ́,+ torí kò kú, ó ń sùn ni.”+ 53 Ni wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ sí í rẹ́rìn-ín, wọ́n sì ń fi ṣẹlẹ́yà, torí wọ́n mọ̀ pé ọmọ náà ti kú. 54 Àmọ́ ó dì í lọ́wọ́ mú, ó sì pè é, ó ní: “Ọmọ, dìde!”+

  • Jòhánù 11:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Jésù sọ fún un pé: “Èmi ni àjíǹde àti ìyè.+ Ẹni tó bá ní ìgbàgbọ́ nínú mi, tó bá tiẹ̀ kú, ó máa yè;

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́