Jòhánù 12:42, 43 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Síbẹ̀, ọ̀pọ̀ nínú àwọn alákòóso pàápàá ní ìgbàgbọ́ nínú rẹ̀ lóòótọ́,+ àmọ́ wọn ò jẹ́ káwọn èèyàn mọ̀ torí àwọn Farisí, kí wọ́n má bàa lé wọn kúrò nínú sínágọ́gù;+ 43 torí pé wọ́n nífẹ̀ẹ́ ògo èèyàn pàápàá ju ògo Ọlọ́run lọ.+
42 Síbẹ̀, ọ̀pọ̀ nínú àwọn alákòóso pàápàá ní ìgbàgbọ́ nínú rẹ̀ lóòótọ́,+ àmọ́ wọn ò jẹ́ káwọn èèyàn mọ̀ torí àwọn Farisí, kí wọ́n má bàa lé wọn kúrò nínú sínágọ́gù;+ 43 torí pé wọ́n nífẹ̀ẹ́ ògo èèyàn pàápàá ju ògo Ọlọ́run lọ.+