Lúùkù 9:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àmọ́ nígbà tí àwọn èrò mọ̀ nípa rẹ̀, wọ́n tẹ̀ lé e. Ó gbà wọ́n tinútinú, ó wá bẹ̀rẹ̀ sí í bá wọn sọ̀rọ̀ nípa Ìjọba Ọlọ́run, ó sì ṣe ìwòsàn fún àwọn tó nílò ìwòsàn.+
11 Àmọ́ nígbà tí àwọn èrò mọ̀ nípa rẹ̀, wọ́n tẹ̀ lé e. Ó gbà wọ́n tinútinú, ó wá bẹ̀rẹ̀ sí í bá wọn sọ̀rọ̀ nípa Ìjọba Ọlọ́run, ó sì ṣe ìwòsàn fún àwọn tó nílò ìwòsàn.+