-
Máàkù 6:45Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
45 Láìjáfara, ó mú kí àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ wọ ọkọ̀ ojú omi, kí wọ́n sì ṣáájú rẹ̀ lọ sí etíkun tó wà ní òdìkejì lápá Bẹtisáídà, òun fúnra rẹ̀ sì ní kí àwọn èrò náà máa lọ.+
-