-
Mátíù 14:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Àmọ́ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, Jésù sọ fún wọn pé: “Ẹ mọ́kàn le! Èmi ni; ẹ má bẹ̀rù.”+
-
-
Máàkù 6:50Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
50 Torí gbogbo wọn rí i, ọkàn wọn ò balẹ̀. Àmọ́ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ó sọ fún wọn pé: “Ẹ mọ́kàn le! Èmi ni; ẹ má bẹ̀rù.”+
-