-
Ẹ́kísódù 33:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Màá tún ṣe ohun tí o ní kí n ṣe yìí, torí o ti rí ojúure mi, mo sì fi orúkọ mọ̀ ọ́.”
-
-
Ẹ́kísódù 33:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Àmọ́ ó tún sọ pé: “O ò lè rí ojú mi, torí kò sí èèyàn tó lè rí mi, kó sì wà láàyè.”
-