Òwe 8:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Jèhófà ṣẹ̀dá mi gẹ́gẹ́ bí ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀nà rẹ̀,+Àkọ́bẹ̀rẹ̀ àwọn àṣeyọrí rẹ̀ ti ìgbà láéláé.+ Òwe 8:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Nígbà náà, mo wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àgbà òṣìṣẹ́.+ Èmi ni àrídunnú rẹ̀+ lójoojúmọ́;Inú mi sì ń dùn níwájú rẹ̀ ní gbogbo ìgbà;+
30 Nígbà náà, mo wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àgbà òṣìṣẹ́.+ Èmi ni àrídunnú rẹ̀+ lójoojúmọ́;Inú mi sì ń dùn níwájú rẹ̀ ní gbogbo ìgbà;+