Lúùkù 9:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ó wá bi wọ́n pé: “Ẹ̀yin ńkọ́, ta lẹ sọ pé mo jẹ́?” Pétérù dáhùn pé: “Kristi ti Ọlọ́run.”+