Jòhánù 2:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ṣùgbọ́n Jésù sọ fún un pé: “Obìnrin yìí, báwo ni ìyẹn ṣe kan èmi àti ìwọ?* Wákàtí mi ò tíì tó.” Jòhánù 7:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Wọ́n wá bẹ̀rẹ̀ sí í wá bí wọ́n ṣe máa mú un,+ àmọ́ ẹnì kankan ò fọwọ́ kàn án, torí pé wákàtí rẹ̀ ò tíì tó.+
30 Wọ́n wá bẹ̀rẹ̀ sí í wá bí wọ́n ṣe máa mú un,+ àmọ́ ẹnì kankan ò fọwọ́ kàn án, torí pé wákàtí rẹ̀ ò tíì tó.+