-
Jòhánù 13:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Jésù mọ̀ pé Baba ti fi ohun gbogbo lé òun lọ́wọ́ àti pé ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni òun ti wá, ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni òun sì ń lọ,+
-
-
Jòhánù 16:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Mo wá bí aṣojú Baba, mo sì ti wá sí ayé. Mo ti wá ń kúrò ní ayé báyìí, mo sì ń lọ sọ́dọ̀ Baba.”+
-